قۇرئان كەرىم مەنىلىرىنىڭ تەرجىمىسى - يورۇباچە تەرجىمىسى- ئەبۇ رەھىمە مىيكائىل

external-link copy
152 : 2

فَٱذۡكُرُونِيٓ أَذۡكُرۡكُمۡ وَٱشۡكُرُواْ لِي وَلَا تَكۡفُرُونِ

nítorí náà, ẹ rántí Mi, Kí N̄g rántí yín.[1] Ẹ dúpẹ́ fún Mi, ẹ má ṣàì moore sí Mi. info

“Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ ẹ̀dá sí Ẹlẹ́dàá ni àwọn iṣẹ́ ìjọ́sìn. Àmọ́ “Ìrántí Allāhu” láti ọ̀dọ̀ Allāhu Ẹlẹ́dàá sí ẹ̀dá ni àwọn ẹ̀san iṣẹ́ ìjósìn.

التفاسير: