Traducción de los significados del Sagrado Corán - Traducción Yoruba - Abu Rahima Mikael

external-link copy
3 : 20

إِلَّا تَذۡكِرَةٗ لِّمَن يَخۡشَىٰ

Bí kò ṣe pé ó jẹ́ ìrántí fún ẹni tó ń páyà (Allāhu). info
التفاسير: