ترجمة معاني القرآن الكريم - الترجمة اليورباوية - أبو رحيمة ميكائيل

سورة الكافرون - Al-Kaafiruun

external-link copy
1 : 109

قُلۡ يَٰٓأَيُّهَا ٱلۡكَٰفِرُونَ

Sọ pé: “Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́, info
التفاسير:

external-link copy
2 : 109

لَآ أَعۡبُدُ مَا تَعۡبُدُونَ

Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún. info
التفاسير:

external-link copy
3 : 109

وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ

Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún. info
التفاسير:

external-link copy
4 : 109

وَلَآ أَنَا۠ عَابِدٞ مَّا عَبَدتُّمۡ

Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́. info
التفاسير:

external-link copy
5 : 109

وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ

Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún. info
التفاسير:

external-link copy
6 : 109

لَكُمۡ دِينُكُمۡ وَلِيَ دِينِ

Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi.” info
التفاسير: