《古兰经》译解 - 约鲁巴语翻译 - 艾布·拉西麦·米卡依赖。

At-Tuur

external-link copy
1 : 52

وَٱلطُّورِ

Allāhu fi àpáta Tūr búra. info
التفاسير:

external-link copy
2 : 52

وَكِتَٰبٖ مَّسۡطُورٖ

Ó tún fi Tírà tí wọ́n kọ n̄ǹkan sínú rẹ̀ búra . info
التفاسير:

external-link copy
3 : 52

فِي رَقّٖ مَّنشُورٖ

(Wọ́n kọ̀ ọ́) sínú n̄ǹkan ìkọ̀wé tí wọ́n tẹ́ ojú rẹ̀ sílẹ̀. info
التفاسير:

external-link copy
4 : 52

وَٱلۡبَيۡتِ ٱلۡمَعۡمُورِ

Allāhu fi Ilé tí àwọn mọlāika ń wọnú rẹ̀ ní ojoojúmọ́ nínú sánmọ̀ búra. info
التفاسير:

external-link copy
5 : 52

وَٱلسَّقۡفِ ٱلۡمَرۡفُوعِ

Ó tún fi àjà tí wọ́n gbé sókè (ìyẹn, sánmọ̀) búra. info
التفاسير:

external-link copy
6 : 52

وَٱلۡبَحۡرِ ٱلۡمَسۡجُورِ

Ó tún fi agbami odò tí wọ́n máa mú iná jáde nínú rẹ̀ búra. info
التفاسير:

external-link copy
7 : 52

إِنَّ عَذَابَ رَبِّكَ لَوَٰقِعٞ

Dájúdájú ìyà Olúwa rẹ máa ṣẹlẹ̀. info
التفاسير:

external-link copy
8 : 52

مَّا لَهُۥ مِن دَافِعٖ

Kò sí ẹni tí ó máa dènà rẹ̀. info
التفاسير:

external-link copy
9 : 52

يَوۡمَ تَمُورُ ٱلسَّمَآءُ مَوۡرٗا

(Ó máa ṣẹlẹ̀) ní ọjọ́ tí sánmọ̀ máa mì tìtì tààrà. info
التفاسير:

external-link copy
10 : 52

وَتَسِيرُ ٱلۡجِبَالُ سَيۡرٗا

àpáta sì máa rìn lọ dànù. info
التفاسير:

external-link copy
11 : 52

فَوَيۡلٞ يَوۡمَئِذٖ لِّلۡمُكَذِّبِينَ

Ní ọjọ́ yẹn, ègbé ni fún àwọn tó pe òdodo ní irọ́, info
التفاسير:

external-link copy
12 : 52

ٱلَّذِينَ هُمۡ فِي خَوۡضٖ يَلۡعَبُونَ

àwọn tí wọ́n wà nínú ìsọkúsọ, tí wọ́n ń ṣeré. info
التفاسير:

external-link copy
13 : 52

يَوۡمَ يُدَعُّونَ إِلَىٰ نَارِ جَهَنَّمَ دَعًّا

(Rántí) ọjọ́ tí wọn yóò máa tì wọ́n lọ́ sínú iná Jahanamọ ní ìtìkutì. info
التفاسير:

external-link copy
14 : 52

هَٰذِهِ ٱلنَّارُ ٱلَّتِي كُنتُم بِهَا تُكَذِّبُونَ

Èyí ni Iná náà tí ẹ̀ ń pè ní irọ́. info
التفاسير: