ការបកប្រែអត្ថន័យគួរអាន - ការបកប្រែជាភាសាយ៉ូរូវ - អាពូ រ៉ហុីម៉ះ មុីកាអុីល

external-link copy
105 : 4

إِنَّآ أَنزَلۡنَآ إِلَيۡكَ ٱلۡكِتَٰبَ بِٱلۡحَقِّ لِتَحۡكُمَ بَيۡنَ ٱلنَّاسِ بِمَآ أَرَىٰكَ ٱللَّهُۚ وَلَا تَكُن لِّلۡخَآئِنِينَ خَصِيمٗا

Dájúdájú Àwa sọ Tírà (al-Ƙur’ān) kalẹ̀ fún ọ pẹ̀lú òdodo nítorí kí o lè máa ṣèdájọ́ láààrin àwọn ènìyàn pẹ̀lú ohun tí Allāhu fi hàn ọ́. Má ṣe jẹ́ olùgbèjà fún àwọn oníjàǹbá.[1] info

1. Kí ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ agbẹjọ́rò má ṣe jẹ́ ẹni tí yóò máa kọ́ ọ̀daràn ní irọ́ nítorí kí ó lè móríbọ́ nínú ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. Kí ẹ̀yin adájọ́ náà má ṣe dá ọ̀daràn láre.

التفاسير: