કુરઆન મજીદના શબ્દોનું ભાષાંતર - યોરૂબા ભાષામાં અનુવાદ - અબૂ રહીમા મિકાઈલ

Al-Falaq

external-link copy
1 : 113

قُلۡ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلۡفَلَقِ

Sọ pé: “Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù info
التفاسير:

external-link copy
2 : 113

مِن شَرِّ مَا خَلَقَ

níbi aburú ohun tí Ó dá,[1] info

1. Allāhu ni Ẹlẹ́dàá gbogbo n̄ǹkan, ohun rere àti ohun burúkú.

التفاسير:

external-link copy
3 : 113

وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ

àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn, info
التفاسير:

external-link copy
4 : 113

وَمِن شَرِّ ٱلنَّفَّٰثَٰتِ فِي ٱلۡعُقَدِ

àti níbi aburú àwọn (òpìdán) tó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè, info
التفاسير:

external-link copy
5 : 113

وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ

àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara.” info
التفاسير: