Firo maanaaji al-quraan tedduɗo oo - Eggo maanaaji Kur'aana e haala Yoruba - Ceerno Abu Rahima Mika'il

external-link copy
57 : 8

فَإِمَّا تَثۡقَفَنَّهُمۡ فِي ٱلۡحَرۡبِ فَشَرِّدۡ بِهِم مَّنۡ خَلۡفَهُمۡ لَعَلَّهُمۡ يَذَّكَّرُونَ

yálà tí ọwọ́ yín bá bà wọ́n lójú ogun, (ẹ fi ìyà tó le koko jẹ wọ́n,) kí ẹ lè (fi ìbẹ̀rù ìyà naa) tú àwọn ọmọlẹ́yìn wọn ká nítorí kí wọ́n lè lo ìrántí; info
التفاسير: